kasahorow Sua,

Yoruba Numbers Zero To 20

Yoruba: Count From Zero To Twenty
nọmba Yoruba
0 oodo

1-10

 • 1 - ọkan
 • 2 - eji
 • 3 - ẹta
 • 4 - ẹrin
 • 5 - arun
 • 6 - ẹfa
 • 7 - eje
 • 8 - ẹẹjọ
 • 9 - ẹsan
 • 10 - mẹwa

11-20

 • 11 - ọọkanla
 • 12 - mejila
 • 13 - mẹtala
 • 14 - ẹrinla
 • 15 - arundinlogun
 • 16 - mẹrindinlogun
 • 17 - mẹtadinlogun
 • 18 - mejidinlogun
 • 19 - mọkandinlogun
 • 20 - ogun

Yoruba Library Books

Get the bilingual activity book for children:

<< Tẹle | Otẹle >>