Nududu,

Irẹẹsi - Waakye

Waakye ni irẹẹsi ti ohunjẹ kan.

Awa nni ifẹ Waakye.

Awa nilo ....

  • irẹẹsi
  • ẹwa
  • tomati
  • ata
  • iyọ
  • alubọsa
  • ẹran tabi ẹja
  • epo
  • gari
<< Tẹle | Otẹle >>