kasahorow Yoruba

Ori, Ejika, Orunkun Ati Ika Ẹsẹ

kasahorow Sua, date(2018-11-22)-date(2024-12-16)

Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.
Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.

Oju, eti, imu ati ẹnu.

Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.
Orunkun ati ika ẹsẹ.

#ori #ejika #orunkun #ika ẹsẹ #oju #eti #imu #ẹnu
Share | Original