kasahorow Sua,

Ori, Ejika, Orunkun Ati Ika Ẹsẹ

Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.
Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.

Oju, eti, imu ati ẹnu.

Ori, ejika, orunkun ati ika ẹsẹ.
Orunkun ati ika ẹsẹ.

<< Tẹle | Otẹle >>